ire de oo

Nov. 13th 06:20 PM 2015
Ogbe Fohun Folohun. Ohun o Fohun folohun.Toba fohun folo un Olohun yomake .Toba fohun folo un Olohun yomore tan han ta han. Adifafun Kumola eyi ti won unpe loyo Apejin. omo Araye sebi oyo Ape pa ni. Ese Ode ni hin A hin A Ese Ode ni hin.lato ni lo hin ayo loro wayojasi. Ibi giga ti ota koro pe Alede.Olodumore gbewa de ibe. Aku ose ogun Orisa Oko Agba irawo yobawa seo (Orin) Orisa oko pele pele dowo re 2* Ododo ifa ko gbodo ku o Orisa oko pele pele dowo re . Aya tofunmi kogbo ku o Orisa Oko pele pele dowo re. Omo tofun mi kogbodo ku o Orisa oko pele pele dowo re .Igba ilemi kogbodo din o Orisa oko pele pele dowo re. Anike tofunmi kogbodo kuo Orisa Oko pele pele dowore . Arike tofunmi kogbodo kuo Orisa Oko pele pele dowo re. Aseooo Awa omo Orisa oko Akupalemo odun Ilasu Awa Omo Odegbola Odejinmi Ajoriwin Gbogbo Omojasu Omobamigbopa Opadere Opayemi Ati bebe lo Awa talasu odun ni lao la temin Orisa oko Agba Irawo yogbe wao Aseooo